Microlophus pacificus, èyí Pacific iguana tí ó wọ́pọ̀ jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù Galápagos ti Pinta.[1] Wọ́n maa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí pọ̀ sí ìdílé Microlophus ṣùgbọ́n wọ́n ti kó wọn sí ẹ̀yà Tropidurus tẹ́lẹ̀.[2]
Microlophus pacificus, èyí Pacific iguana tí ó wọ́pọ̀ jẹ́ àwọn ẹ̀yà alángba àpáta tí ó wọ́pọ̀ ní erékùṣù Galápagos ti Pinta. Wọ́n maa ń kó àwọn ẹ̀yà wọ̀nyí pọ̀ sí ìdílé Microlophus ṣùgbọ́n wọ́n ti kó wọn sí ẹ̀yà Tropidurus tẹ́lẹ̀.